Overview
Aremu enjoyed the happiness of a rich family before the demise of his father when he was only a young boy in elementary school. He was thereafter confronted with various challenges of life. His relentless effort was eventually rewarded leading to a rich, beautiful life which led to celebration. The book is indeed a product of a wordsmith. Aremu weaves life experiences just with words as a blacksmith forges working implements. It is full of wits, anecdotes and humor peculiar of the Yoruba language and culture.The book also contains questions and answers part to help the understanding of Yoruba students. It is recommended for all lovers of Yoruba Language. YORUBAÀrẹ̀mú pàdánù bàbá rẹ̀ nígbà tó wà ní màjẹ̀sín, o sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdojúkọ àti ìrírí ayé nínú ìrìn àjò rẹ̀ láti gòkè àgbà. Ṣe ìrírí ayé kìí fini títí kó fini pa, ọgbọ́n ló fi nkọ́ ni. Àrẹ̀mú kò rẹ̀wẹ̀sì nínú làásìgbò yìí, ó sì jèrè ìforítì. Inú ẹni kìí dùn ká paá mọ́ra. Ẹsẹ̀ tó nà báyìí, ijó ló fàá. Kò sóhun tóle tí kìí dẹ̀. Ọ̀rọ̀ ni Àrẹ̀mú fi rọ ìrírí ayé kalẹ̀ bí ìgbà ti alágbẹ̀dẹ rọ ọkọ́ àti àdá nínú ìwé yìí. Bẹ́ẹ̀ni àsà àti ìṣe Yorùbá pẹ̀lú ẹ̀kọ́ àti àwàdà ọ̀kan-ò-jọ̀kan kún inú Àrẹ̀mú Alágbẹ̀dẹ Ọ̀rọ̀. Bákannáa ni àwọn ìbéèrè wà lórí ìwé yìí fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́. Àkàgbádun sìni fún gbogbo ènìyàn.
- | Author: Olatinwo Adeagbo Fatoki
- | Publisher: Independently Published
- | Publication Date: Dec 22, 2021
- | Number of Pages: 96 pages
- | Binding: Paperback or Softback
- | ISBN-13: 9798788684550