null Skip to main content

✨ Buy more, save 5% Ends

Ọlọ́run, Níbo Lo Wá?

Ọlọ́run, Níbo Lo Wá?

Was: $15.99
Now: $14.46
(No reviews yet) Write a Review
Physical book delivery

Shipping calculated at checkout.

Estimated delivery
Adding to cart… The item has been added
Product Details
Author:
Adeola Oreoluwa Adefeso
Publisher:
Iem Press
Publication Date:
Nov 22, 2021
Number of pages:
114 pages
Binding:
Paperback or Softback
ISBN-10:
1636031226
ISBN-13:
9781636031224

Overview

A bí Adéọlá Ọrẹolúwa Adéfẹ̀sọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ṣe èwe rẹ̀ nínú ayọ̀ àti ìdùnnú. Àwọn òbí rẹ̀ àgbà ní ìdílé ìyá ló tọ́ ọ dàgbà pẹ̀lú ìfẹ́ tó wàyàmì àti ẹ̀kọ́ ìwé tó yè kooro, òun náà sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akọrin agbègbè ibẹ̀. Ṣùgbọ́n nǹkan yí bìrí nígbà tí ó kó sí wàhálà abẹ́ ilé látàrí ìjìyà tí ó ń rí láti ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀. Inú làásìgbò ìjìyà ara àti ọkàn yìí ló wà tí ó fi pàdánù àwọn ìbejì ọkùnrin rẹ̀ méjèèjì tí ó bí ní kògbókògbó.Nínú ọdún 2019, ọmọkùnrin rẹ̀, àbísìkejì, tí ó fìgbà kan jẹ́ ọmọ ogun ojú omi ilẹ̀ Amẹ́ríkà náà tún pa ara rẹ̀. Lẹ́yìn èyí ni Adéọlá tún rí àwọn ọ̀rọ̀ kòbákùngbé tí ọkọ rẹ̀ kọ nípa rẹ̀ sí orí ẹ̀rọ ayélujára kà dé ibi pé òun lòun fa ikú ọmọ àwọn ọ̀hún.Ìrora, ìfẹ́, àti ìgbàgbọ́ Adéọlá fara hàn kedere nínú ìtàn àgbọ́gbárímú yìí tí ó gbé kalẹ̀ ní ìrètí pé yóò dé etígbọ̀ọ́ àwọn tí yóò wúlò fún."Nínú ìwé yìí, Adéọlá gbé ìtàn akíkanjú obìnrin kan tí ó dojú kọ wàhálà abẹ́le kalẹ̀. Lẹ́yìn-ò-rẹyìn, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run, ó jáwé olúborí." Iloh, Friday Okechukwu (Ph. D)


  • | Author: Adeola Oreoluwa Adefeso
  • | Publisher: Iem Press
  • | Publication Date: Nov 22, 2021
  • | Number of Pages: 114 pages
  • | Binding: Paperback or Softback
  • | ISBN-10: 1636031226
  • | ISBN-13: 9781636031224

Reviews

0 Reviews

Write a Review

No reviews yet.

Share your experience and help another reader choose their next book.

Discover your next great book

Get new releases, reader favourites, and special offers delivered to your inbox.